AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language
Ẹ kọ Software Testing Ati Automation, Test Analyst, QA Tester, Software Test Engineer ati bẹ bẹ lọ ni ede Yoruba
4.55 (33 reviews)

85
students
6.5 hours
content
Aug 2018
last update
$19.99
regular price
What you will learn
Ninu ẹkọ yi, a o kọ lati Setup Working Environment fun Software Testing ati Automation
A o kọ In and Out Functional Testing fun Web Application, Mobile Apps Ati Desktop Applications
A o kọ lati lo SQL Server Management Studio (SSMS) lati Query SQL Server Database
A o kọ lati lo Selenium WebDriver fun Automating Web Applications
A o kọ lati lo Java Eclipse Integration Development Environment (IDE) pẹlu Selenium WebDriver
A o kọ lati lo Exploratory Testing
A o kọ lati lo SQL Server Integration Services (SSIS) lati Upload Data sinu SQL Server Database
A o kọ nipa Basic Microsoft Excel (Spreadsheet) ati Microsoft Word (Document) Object fun Creating Simple Dashboard
A o kọ bi a o ṣe Migrate Microsoft Access Database lọ si MSSQL Server Database
A o kọ Data Migration Testing
A o kọ lati le Report Bugs Tabi Defects
A o kọ End To End Testing
A o kọ Regression Testing
A o kọ lati lo MSSQL Server Database fun Extract Transform Load (ETL Testing) ati Database Testing
A o kọ lati le Create Test Script Template pẹlu Microsoft Excel fun Desktop, Mobile ati Web Applications
A o kọ lati Gain Working Experience As a Primary Tester at bẹ bẹ lọ
Screenshots




Related Topics
1207238
udemy ID
5/7/2017
course created date
9/1/2020
course indexed date
Bot
course submited by